audio
audioduration (s)
1.54
28.9
sentence
stringlengths
17
265
[snap] Àgùntàn l’ẹranko tó gọ̀ jù.
Ọ̀gá kan ní báńkì rí ẹ̀wọ̀n ọdún méta he nítorí jìbìtì
Ó ṣeni láàánú pé tí o bá ṣe DVD, eteti rẹ náà ṣe é ṣe kí ó gé kúrò pẹ̀lú, tí fídíò náà bá ní àdàkọ sií èdè mìíràn tí o sì súnmọ́ abẹ́, wọn ò ní hàn dáadáa.
[snap] Ṣé o ti jẹ ẹran ajá rí.
Odo Onega naa ha mo Folga, tori na o seese ki o fi Rosia wa lati Okun Kaspiani.
Àwọn ọlọ́pàá ilẹ̀ New Zealand ní ìṣòro lílo ìbọn speed radar wọn láti rí bí Ọ̀gbẹ́ni Reid ṣe ń sáré tó, nítorí bí ẹwà ẹ̀nìyàn dudu ti ri, ẹ̀ẹ̀kan soso tí àwọn ọlọ́pàá yóò rí bí Ọgbẹ́ni Reid ṣe ń sáré sí ni ìgbà tí Ó sinmi díẹ̀, èyi ni ọgọ́ta kìlómíta láàrin wákàtí.
[breath] Bàbá mi gbọ́ òyìnbó ̣sùgbọ́n kò fi bẹ́ẹ̀ mọ̀ọ́ sọ.
Ẹ̀dá Onílé-olá ṣàlàyé lori fíìmù "Ògbórí Ẹlẹ́mọ̀ṣọ́".
Ẹ̀sìn gbòógì tó wà ní Moldova ni ẹ̀sìn kìrìsìsítíẹ́nì elérò tótọ́.
Tori naa pensu naa je ore to dara si eyan pupo nigbati o jade.
Ẹ̀bùn ńlá ni ìjọba fi ta ìyá tó pàdánù ọmọ rẹ̀ lásìkò ìwọ́de lọ́rẹ.
Bí àwọn iléèwé gíga ní ibòmíràn ṣe rí gan ni àwọn náà rí.
Koríko ni ewúré máa ń jẹ.
Ọbásanjọ́ sọ pé Nàìjíríà yóò ṣẹ́gun ìpèníjà tó ń dojú kọ wá
Àjàkálẹ̀ ààrùn ní èyí tí pátójìnì, bí í àwọn kòkòrò ààrun tí a kò lè fojúrí lọ́lọ́kan ò jọ̀ka.
Iléeṣẹ́ ààrẹ lórí gbèdéke tó fáwọn darandaran.
Ó farapẹ́ra ṣùgbọ́n ní ọ̀pọ̀ ìgbà kií lọ pẹ̀lú àrà ski alpine tàbí òkè gígùn, èyí tí ó kẹ́yìn máa wáye ní òkè tó ń yọ̀ tí ó sì nílò ohun tó tọ́ àti búùtù púpọ.
Bí gbogbo Ibi ìgbafẹ́ South Africa, owó ìlẹlé jẹ́̀fẹ́ àwọn oríṣiríṣi ǹkan ló sì wà níbẹ̀.
Torina o seese pe won fi akosile naa se lebeeli lasan.
Àwọn erekùsù ìlà oòrùn adúláwọ̀ wà ní òkun India ní ìlà oòrùn adúláwọ̀.
Mo ní kí wọ́n yé ṣe àwáwí fún bàbá Ìjẹ̀shà fún oun tó ṣẹ
Oòni Adéyẹyè àti Olòrì rẹ̀ gbé Àrẹ̀mọ tuntun wọ ṣọ́ọ̀ṣì.
Ìwé mẹ́rin ni ọ̀gbẹ́ni Caleb ní ka rà.
Bùhárí sọ pé òun gbé àwọn ìgbésẹ̀ náà nítorí ìjàm̀bá ọkọ̀.
Montevideo wà ní ilé olóoru; ní àwọn oṣù àkókò eèrùn, ìwọ̀n ooru tó má ń wọ́pọ̀ ni èyí tó ma ń ju +30°C lọ.
Yorùbá yóò gba òmìnira láìpẹ́, ó dá mi lójú.
Aya rere l’ọ́dẹ̀dẹ̀ ọkọ ni Ṣọlá.
Angelin (2006) sàlàyé pe ọ̀nà ìṣe Kontinuumi jẹ́ ìgbésẹ̀ tí à n fi bá àwọn ilé ìṣẹ́ dẹ́ ipò ìṣe gíga.
Aà jí ire bí, ẹ̀yin ọmọ Oòduà?
Adélékè ló wọlé nínú ètò ìdìbò tó wáyé ní ìlú Ọ̀sun.
Adìyẹ kan yàgbé sí orí ọkọ̀ mi.
Mo ti gbọ́ ìmọ̀ràn ẹ.
Àwọn bàbá bàbá wọn Ostralopitekusi ò dúró rìn.
[breath] [snap] A ò ní rìn ní ọjọ́ tí ebí ń pa ọ̀nà. [external]
NHK ròyìn pe Ilé ìgbìn agbára nukilia Kaṣiwasaki Kariwa ni Nigata kí ń ṣiṣẹ́ dédé tẹ̀lé.
Ọmọ ọdún méjìlá kan ló fò sílẹ̀ láti orí ilé gíga
Iṣẹ́ èní gba omi mu.
Àga irú èyí tí àwọn òyìnbó máa ń lò ni ó wà nílé Ọ̀túnba.
Abíọ́lá sọ pé bàbá òun jẹ́ aránṣọ, tí ìyá òun sì jẹ́ ọlọ́jà wóróbo.
Kí lo dé tí ìpànìyàn àti ìdigunjalè ń peléke síi lábẹ́ Mákindé?
Ẹlẹ́dẹ̀ náà bí ọmọ mẹ́fà péré.
Mo máa wà ní agbègbè Tinúbú ní agogo mẹ́wa ọ̀la.
Ààyè tí ó wà láàrin Point Marion àti Fairmont se àfihàn àwọn ìpènijà àwọn awakọ̀ ní ojú ọ̀nà márosẹ̀ Buffalo-Pittsburgh, ní gbogbo igbà tí wọ́n bá gba àwọn ojú òpó tó dáwà kọjá.
Ìkan lára àpẹrẹ́ má le gbàgbé ti ìkéde North Atlantic ti WWII. Àwọn Amẹ́ríkà ń gbìyànjú láti gbé àwọn ọkùnrin àti àwọn ǹkan èlò kọjá Atlantic Ocean láti ran Britain lọ́wọ́.
O le ka bi igba se n lo fun ara re ko maa wo bi isele ayipo se tun sele. Isele ayipo je nkan to ma n saba sele leemewa si.
Mínístà fún ọ̀nà ìbáraẹnisọ̀rọ̀ ti gba àṣẹ nítorí ọ̀rọ̀ tó sọ
Nǹkan àmúṣagbára ìṣẹ̀mbáyé ilẹ̀ Yorùbá ṣì wà bíi ti àtijọ́.
Ṣẹwẹlẹ jẹ lítíréṣọ̀ alóhun tó ń ṣe pẹ̀lú orin kíkọ, ìlù lílù, ìjó jíjó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.
Chiao àti Sharipov fi tónilétí pé ó dára láti jíjìnà sí ẹnjìni tí a mọ̀ sí attitude adjustment thruster.
Àwọn olólùfẹ́ Ronkẹ́ Ìdídowó ti ń fọnmú lórí èsì àyẹ̀wò.
A le lo ẹ̀rọ ayárabíàṣá láti ya àwọn Awòrán ìgbàlódé tó jẹ ojú ni gbèsè, àwọn irúfẹ́ àwòrán wọ̀nyí ni wọ́n ń lo ní orí amóhùnmáwòrán àti ní inú àgbéléwò báyìí.
Àwọn ẹbí Àjàgbé bèrè fún ìwádìí òótọ́ lórí ikú ọmọ wọn.
Àt’àná ni mo ti ń sùn.
[breath] Àlùbọ́sà ni ó ń tà.
Mẹ́fà nínú àwọn akẹ́kọ̀ọ́ wa ti kú sí àkàtà àwọn ajínigbé.
Ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó ti ti Ọjà Ládọjà pa.
Ìdá méjìdílógún àwọn èèyàn ilẹ̀ Venezuela ni kò ní iṣẹ́, ọ̀pọ̀ àwọn tó sì níṣẹ́ ló ń siṣẹ́ ní ẹka ọrọ̀ ajé tí kìí se fọ́mà.
Ìlù àti agogo máa ń sábà jẹyọ nínu orin.
[breath] [snap] Bí ọmọ yìí ṣe máa ń sọ̀rọ̀ máa ń múmi lọ́kàn.
Ó kọjá èyan milionu mẹ́rin tó lọsí Romu fún ìsìnkú náà.
Ọdúnladé Adékọ́lá fẹ́ ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú Tóyìn Bọ́látifẹ́.
[snap] Sọ ọ̀rọ̀ òṣèlú tàbí ìwà ìbàjẹ́ nínú àwùjọ.
Òṣèlú kìí ṣe eré ọmọdé rárá rárá.
A fẹ́ lọ ra omi ní ọjà Baṣọ̀run.
Fun afiwe ti o ma ya awon èèyàn pupo lenu:iye awon ara Ilu Amerika tio wa lati ile Afirika, po ju awon omo bibi ilu Canada lọ.
[breath] Ṣọ̀pọ̀ná ò ní mọ ‘lé wa o. Àmin.
O ní àgbẹkalẹ̀ mólíkuúlà kan náà yálà o jẹ aféfé gaasi, olómi, tàbí ní lìlẹ.
Ọkùnrin àti obìnrin tí kò ní ìbálòpọ̀ kò lè bímọ
Ìbọn jẹ́ irinṣẹ́ pàtàkì fún àwọn ọde.
Ìjàmbá ọkọ̀ agbépo mú ẹ̀mí ènìyàn kan lọ ní ìlú Èkó.
Ni aago kàn kojá ìséjú márùndínlógún gégé bi ẹlẹri, ọkò akérò náà lọ níbi iná aláwọ ewé, nígbàtí ọkọ̀ ayọ́kélẹ´ náà yíwọ́ níwájú rẹ̀.
Akẹ́kọ̀ọ́ wa kú lẹ́yìn tó ti ilé ọ̀rẹ́kùnrin rẹ̀ dé.
Láti ìgbàyẹn, àwọn Brasili ti kópa ní eré 53 fún ẹgbẹ́ ní gbogbo ìdíje wọ́n dẹ̀ ti gbá goolu 24.
Àwọn ọlọ́re Mangola Medicien Sans Frontieres àti Ile Iṣe Ìlera Ìgbìmọ̀ Àgbáyé, wípé ìbẹ́sílẹ̀ àrùn naa lo buru jù ní gbogbo ìlú.
Ààrẹ sọ fún àwọn ọmọ Nàíjíríà kí wọn ó ní sùúrù.
O le din owo kun fun e ju ki o ra maapi titun fun GPS abi GPS to wa ninu ero adawa tabi yiyalo iikan lati owo ile ise to ma n ya moto.
Amòfin Adé lérí láti gbé Ìjọba lọ ilé ẹjọ́.
Kí ló ń fàá tí Kúnlé fi ń bínú sí gbogbo ará àdúgbò?
Abẹ́rẹ́ mẹ́ta ni ó gbà sí apá rẹ̀.
Elétí kunkun ni Túndé.
Ọlá gbà pé òun jẹ̀bi ẹ̀sùn kíkó owó pamọ̀ lọ́nà àìtọ́.
Bọ́lá Tinúbú kò rán ẹnikẹ́ni níṣẹ́ láti bá òun polongo ìbò
Ṣé Ìgbòho ṣetán láti ṣe ìpàdé pẹ̀lú Ṣèyí Mákindé àti ọlọ́pàá?
Agboọlá Àjàyí ní mílíọ̀nù mẹ́wàá lòun ń gbà lóṣù.
[snap] Kílàsì àkọ́kọ́ ni a ti kọ́ nípa Fonọ́lọ́jì.
Nàíjíríà sì ń dojúrú lọ, a sì ń wòran báyìí.
Ó yẹ́ kí o fi sùúrù yan ilé iṣẹ́ ọkọ̀ òfurufú r.
Lílọ-bíbọ̀ ìrìnnà ní ìwádìí ìrìnkèrindò àwọn awakọ kọ̀ọ̀kan àti ipò òkàn kan sí òmíràn ní agbẹdẹ méjì pélù ìbásẹpọ̀ tí wọn ní sí ara wọn.
Inú àbótí ńlá ni Àjàní kó gbogbo àwọn aṣọ rẹ̀ sí.
Dókítà Ehud, akọ́ṣẹmọṣẹ́ ìmọ̀ ogun ní ilé ẹ̀kọ́ gíga Dalhousie ní Halifax, Nova Scotia àti alága ìpín ti ìṣègùn àti ìmọ̀ síẹ̀nsì ti Ẹgbé Ìtọ ṣúggà ti Ará Ìlú Canada sọ pé ìwádìí náà ṣì jẹ́ tuntun.
Fálọ́wọ̀ fẹ́ ṣe ìyàwó alárédè lẹ́yìn tí òun bá dé ipò.
Ọmọ yìí fi ewúrẹ́ rúbọ bí babalawo ti sọ fún un. [external]
[breath] Tírélà náà ti dànù sí òpópónà Àpápá.
Wá bá mi re èékán mi.
Ọkọ̀ ojú irin agbègbè ní ìpele méjì fún àwọn olùrìnrìn ojú irin nínú àti lágbègbè Cape Town: Metroplus (ti wọ́n tún ń pè ní ìpele àkọ́kọ́) àti Metro ( tí wọ́n pè ní ìpele kẹta.
Àwọn èrò ìlú Vatican tó bí i ẹgbẹ̀rin. ó jẹ́ ìlú olómìnira kékeré kan lágbàláayé àti orílèèdè tó ní èrò tó kéré jù.
Àwọn ènìyàn tó ní irú ìrònú yìí ní ọpọlọ, wọ́n sì lè gbé ǹkan sórí, wọ́n lè yànjú ìṣòro wọ́n sì lè ṣiṣẹ́ lórí ìdánwò síẹ́nsì.
Ohun tí ó dára ni láti wà pẹ̀lú enìkan tì èèyàn fẹ́ràn.
Iléèwé ni wọ́n ti kọ́kọ́ pàdé ara wọn kí wọ́n tó fẹ́ ara wọn
Dáramọ́la Abíọ́dún tó jé agbenusọ fún ìjọba ló ṣẹ̀ṣẹ̀ dé